Léfítíkù 25:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Bí ọ̀kan nínú àwọn ènìyàn yín bá talákà, débi pé ó ta ara àwọn ẹrù rẹ̀, kí ará ilé rẹ̀ tí ó sún mọ́ ọ ra ohun tí ó tà padà.

Léfítíkù 25

Léfítíkù 25:19-33