Léfítíkù 25:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi ó pèsè ìbùkún sórí yín tóbẹ́ẹ̀ tí ilẹ̀ yín yóò so èso tó tó fún ọdún mẹ́ta lẹ́yìn rẹ̀.

Léfítíkù 25

Léfítíkù 25:11-26