Léfítíkù 25:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Bí ẹ bá ta ilẹ̀ fún ọ̀kan nínú àwọn ènìyàn yín tàbí bí ẹ bá ra èyíkéyí láti ọ̀dọ̀ rẹ̀, ẹ má ṣe rẹ́ ara yín jẹ.

Léfítíkù 25

Léfítíkù 25:13-23