Léfítíkù 24:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ fi ojúlówó tùràrí sí ọnà kọ̀ọ̀kan, gẹ́gẹ́ bí ìpín ìrántí láti dípò àkàrà, àti láti jẹ ẹbọ ọrẹ iná sísun fún Olúwa.

Léfítíkù 24

Léfítíkù 24:5-11