Léfítíkù 24:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọmọkùnrin kan wà tí ìyá rẹ̀ jẹ́ ọmọ Ísírẹ́lì baba rẹ̀ sì jẹ́ ará Éjíbítì. Ó jáde lọ láàrin àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, ìjà sì ṣẹlẹ̀ nínú àgọ́ láàrin òun àti ọmọ Ísírẹ́lì kan.

Léfítíkù 24

Léfítíkù 24:1-15