Léfítíkù 23:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ kò gbọdọ̀ ṣe iṣẹ́ kankan rárá. Èyí yóò jẹ́ ìlànà ayérayé fún àwọn ìran tí ń bọ̀, níbikíbi tí ẹ bá ń gbé.

Léfítíkù 23

Léfítíkù 23:22-39