Léfítíkù 22:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹni náà tí ó fọwọ́ kan irú nǹkan bẹ́ẹ̀ yóò di aláìmọ́ títí ìrọ̀lẹ́. Kò gbọdọ̀ jẹ èyíkéyí nínú ọrẹ mímọ́ àyàfi bí ó bá wẹ ara rẹ̀.

Léfítíkù 22

Léfítíkù 22:1-7