Léfítíkù 22:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nípa fífi ààyè fún wọn láti jẹ ọrẹ mímọ́ náà, kí wọ́n sì tipa bẹ́ẹ̀ mú ẹ̀bi tí wọn yóò san nǹkan fún wá sórí wọn. Èmi ni Olúwa, tí ó sọ wọ́n di mímọ́.’ ”

Léfítíkù 22

Léfítíkù 22:15-22