Léfítíkù 22:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ọmọbìnrin àlùfáà bá fẹ́ ẹni tí kì í ṣe àlùfáà, kò gbọdọ̀ jẹ nínú èyíkéyi nínú ohun ọrẹ mímọ́.

Léfítíkù 22

Léfítíkù 22:7-14