Léfítíkù 21:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ó ma ṣe wọlé tọ òkú lọ, kí ó má ṣe sọ ará rẹ di àìmọ́ nítorí baba tàbí nítorí ìyá rẹ̀.

Léfítíkù 21

Léfítíkù 21:4-13