Léfítíkù 21:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa sọ fún Mósè wí pe, “Bá àwọn àlùfáà tí wọ́n jẹ́ ọmọ Árónì sọ̀rọ̀, kí o sì sọ fún wọn pé: ‘Ẹnikẹ́ni nínú wọn kò gbọdọ̀ sọ ara rẹ̀ di aláìmọ́ nítorí àwọn ènìyàn wọn tí ó kù.

Léfítíkù 21

Léfítíkù 21:1-5