Léfítíkù 20:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ gbọdọ̀ jẹ́ mímọ́ fún mi torí pé èmi Olúwa fẹ́ mímọ́. Mó sì ti yà yín kúrò nínú àwọn orílẹ̀ èdè yòókù kí ẹ le jẹ́ tèmi.

Léfítíkù 20

Léfítíkù 20:16-27