Léfítíkù 2:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ó bá jẹ́ inú àwo pẹẹrẹ ni o ti se ohun jíjẹ rẹ, kí ó jẹ́ ìyẹ̀fun dáradára tí a fi òróró pò, kò sì gbọdọ̀ ní ìwúkàrà.

Léfítíkù 2

Léfítíkù 2:1-12