Léfítíkù 2:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìyòókù nínú ọrẹ ohun jíjẹ yìí jẹ́ ti Árónì àti àwọn ọmọ rẹ̀, ó jẹ́ èyí tí ó mọ́ jùlọ nínú ọrẹ tí a fi iná sun sí Olúwa.

Léfítíkù 2

Léfítíkù 2:5-16