Léfítíkù 19:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọjọ́ tí ẹ bá rú u náà ni ẹ gbọdọ̀ jẹ ẹ́ tàbí ní ọjọ́ kejì; èyí tí ó bá sẹ́kù di ọjọ́ kẹta ni kí ẹ fi iná sun.

Léfítíkù 19

Léfítíkù 19:2-7