Léfítíkù 19:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Ẹ má ṣe titorí òkú, gé ibi kankan nínú ẹ̀yà ara yín, Ẹ kò sì gbọdọ̀ sín gbẹ́rẹ́ kankan. Èmi ni Olúwa.

Léfítíkù 19

Léfítíkù 19:23-32