Léfítíkù 16:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun yóò sì wọ aṣọ funfun mímọ́ pẹ̀lú àwọ̀tẹ́lẹ̀ funfun, yóò sì fi àmùrè funfun mímọ́ dì í: yóò sì dé fìlà funfun: àwọn aṣọ mímọ́ nìwọ̀nyí: Òun yóò sì fi omi wẹ̀, kí ó tó wọ̀ wọ́n.

Léfítíkù 16

Léfítíkù 16:1-9