Léfítíkù 16:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọ̀dọ́ akọ màlúù àti ewúrẹ́ ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ tí a ti mú ẹ̀jẹ̀ wọn wá sí ibi mímọ́ jùlọ ni kí a gbe jáde kúrò ní ibùdó. Awọ wọn ni a ó fi iná sun bákan náà.

Léfítíkù 16

Léfítíkù 16:17-34