Léfítíkù 16:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yóò sì fi omi wẹ ara rẹ̀ ní ibi mímọ́ kan: yóò sì wọ aṣọ rẹ̀ yóò sì wá ṣí iwájú: yóò sì rú ẹbọ sísun ti ara rẹ̀ àti ti àwọn ènìyàn láti ṣe ètùtù fún ara rẹ̀ àti fún àwọn ènìyàn:

Léfítíkù 16

Léfítíkù 16:15-26