Léfítíkù 16:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ewúrẹ́ náà yóò sì ru gbogbo àìṣedédé wọn lọ sí ilẹ̀ tí ènìyàn kò gbé. Òun yóò sì tú ewúrẹ́ náà sílẹ̀ ní àṣálẹ́.

Léfítíkù 16

Léfítíkù 16:16-27