Léfítíkù 16:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yóò sì mú nínú ẹ̀jẹ̀ ọmọ màlúù náà yóò sì fi ìka rẹ̀ wọ́n ọn, ní iwájú ìtẹ́ àánú, yóò sì fi ìka rẹ̀ wọ́n ọn nígbà méje níwájú ìtẹ́ àánú.

Léfítíkù 16

Léfítíkù 16:10-23