Léfítíkù 16:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Árónì yóò sì mú akọ màlúù fún ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ wá láti ṣe ètùtù fún ara rẹ̀ àti ìdílé rẹ̀. Yóò sì pa akọ màlúù náà fún ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ tirẹ̀.

Léfítíkù 16

Léfítíkù 16:7-17