Léfítíkù 15:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹnikẹ́ni tí ó bá joko lórí ohunkóhun tí ọkùnrin tí ó ní ìṣunjáde bá jókòó le gbọdọ̀ fọ aṣọ rẹ̀: kí ó sì wẹ̀, kí ó sì wà láìmọ́ títí di ìrọ̀lẹ́.

Léfítíkù 15

Léfítíkù 15:1-14