Léfítíkù 15:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yálà ó ń jáde léraléra tàbí ó dúró, èyí yóò sọ ọ́ di aláìmọ́. Báyìí ni ìṣunjáde rẹ̀ ṣe le è sọ ọ́ di aláìmọ́.

Léfítíkù 15

Léfítíkù 15:1-7