Léfítíkù 15:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìbáà se ibùsùn tàbí ohunkóhun tí ó jókòó lé. Ẹnikẹ́ni tí ó bá fọwọ́ kàn án yóò jẹ̀ aláìmọ́ títí di ìrọ̀lẹ̀.

Léfítíkù 15

Léfítíkù 15:14-26