Léfítíkù 14:51 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ó ri igi sídà, hísópù, òdòdó àti ààyè ẹyẹ náà bọ inú ẹ̀jẹ̀ òkú ẹyẹ àti omi tí ó mọ́ náà kí ó fi wọ́n ilẹ náà lẹ́ẹ̀méje.

Léfítíkù 14

Léfítíkù 14:50-57