Léfítíkù 14:48 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Bí àlùfáà bá wá yẹ̀ ẹ́ wò tí àrùn náà kò gbilẹ̀ mọ́ lẹ́yìn tí a ti rẹ́ ilé náà: kí àlùfáà pe ilé náà ní mímọ́, torí pé àrùn náà ti lọ.

Léfítíkù 14

Léfítíkù 14:43-55