Léfítíkù 14:45 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wíwó ni kí a wó o, gbogbo òkúta ilé náà, àwọn igi àti gbogbo ohun tí a fi rẹ́ ẹ ni kí a kó jáde nínú ìlú sí ibi tí a kà sí àìmọ́.

Léfítíkù 14

Léfítíkù 14:44-53