Léfítíkù 14:42 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òkúta mìíràn ni kí wọ́n fi dípò àwọn tí a ti yọ dànù kí wọ́n sì rẹ́ ilé náà pẹ̀lú àwọn ohun ìrẹ́lé tuntun.

Léfítíkù 14

Léfítíkù 14:38-44