Léfítíkù 14:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Kí àlùfáà mú ọ̀kan nínú àwọn àgbò àti òróró kí ó sì fi rú ẹbọ ẹbí. Kí ó sì fí wọn níwájú Olúwa gẹ́gẹ́ bí ẹbọ fífí.

Léfítíkù 14

Léfítíkù 14:5-21