Léfítíkù 13:54 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ó pàṣe pé kí wọ́n fọ ohunkóhun tí ó bàjẹ́ náà kí ó sì wà ní ìpamọ́ fún ọjọ́ méje mìíràn.

Léfítíkù 13

Léfítíkù 13:44-57