Léfítíkù 13:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí àpá ara rẹ̀ bá funfun tí ó sì dàbí ẹni pé kò jinlẹ̀ jù awọ ara, tí irun rẹ̀ kò sì yípadà sí funfun kí àlùfáà fi ẹni náà pamọ́ fún ọjọ́ méje.

Léfítíkù 13

Léfítíkù 13:1-11