Léfítíkù 13:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Bí àrùn náà bá ràn yíká gbogbo awọ ara rẹ̀ tí àlùfáà sì yẹ̀ ẹ́ wò, tí ó rí i pé àrùn náà ti gba gbogbo ara rẹ̀ láti orí títí dé ẹṣẹ̀,

Léfítíkù 13

Léfítíkù 13:2-13