Léfítíkù 11:45 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi ni Olúwa tí ó mú yín jáde láti ilẹ̀ Éjíbítì wá láti jẹ́ Ọlọ́run yín torí náà, ẹ jẹ́ mímọ́ torí pé mímọ́ ni èmi.

Léfítíkù 11

Léfítíkù 11:43-47