Léfítíkù 11:37 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí òkú ẹranko wọ̀nyí bá bọ́ sórí ohun ọ̀gbìn tí ẹ fẹ́ gbìn wọ́n sì jẹ́ mímọ́.

Léfítíkù 11

Léfítíkù 11:35-45