Léfítíkù 11:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Olúwa sọ fún Mósè àti Árónì pé,

2. “Ẹ sọ fún àwọn ara Ísírẹ́lì pé, ‘Nínú gbogbo ẹranko tí ń gbé lórí ilẹ̀ àwọn wọ̀nyí ni ẹ le jẹ.

3. Gbogbo ẹranko tí pátakò ẹsẹ̀ rẹ̀ bá là tí ó sì ń jẹ àpọ̀jẹ.

Léfítíkù 11