Léfítíkù 10:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè pe Másáélì àti Élísáfánì ọmọ Yúsíélì tí í ṣe arákùnrin Árónì, ó sọ fún wọn pé “Ẹ wá, kí ẹ sì gbé àwọn arákùnrin yín jáde kúrò níwájú ibi mímọ́ lọ sí ẹ̀yìn ibùdó.”

Léfítíkù 10

Léfítíkù 10:1-10