Kólósè 4:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun sì ń bọ̀ pẹ̀lú Ónísímù, arákùnrin olóòótọ́ àti olùfẹ́, ẹni tí í ṣe ọ̀kan nínú yín. Àwọn ní yóò sọ ohun gbogbo tí à ń ṣe níhìn-ín-yìí fún un yín.

Kólósè 4

Kólósè 4:7-18