Kólósè 3:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà, bí àyànfẹ́ Ọlọ́run, ẹni mímọ́ àti olùfẹ́, ẹ gbé ọkàn ìyọ́nú wọ̀, ìsoore, ìrẹ̀lẹ̀, inú tútù àti sùúrù.

Kólósè 3

Kólósè 3:11-16