Kólósè 2:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì ti já àwọn aláṣẹ àìrí àti àwọn alágbára, ó ń yọ̀ fún ìṣẹ́gun lórí wọn nínú rẹ̀.

Kólósè 2

Kólósè 2:7-16