Kólósè 2:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti ẹ̀yin, ẹni tí o ti kú nítorí ẹ̀ṣẹ̀ yín àti àìkọlà ará yín, mo ni, ẹ̀yin ni ó sì ti sọ di ààyè pọ̀ pẹ̀lú rẹ̀, ó sì ti dárí gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ yín jì yín;

Kólósè 2

Kólósè 2:11-21