Kólósè 1:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwa ń wàásù rẹ̀, a ń gbani níyànjú a sì ń kọ olúkúlùkù ènìyàn ní ọgbọ́n gbogbo, kí a lè mú olúkúlùkù dé ọ̀dọ̀ Ọlọ́run ní pípé nínú Kírísítì.

Kólósè 1

Kólósè 1:26-29