Kólósè 1:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó ti pa àsírí ìjìnlẹ̀ yìí mọ́ fún ayérayé àti láti ìrandíran. Ṣùgbọ́n nísinsin yìí, gẹ́gẹ́ bí ìfẹ́ ọkàn rẹ̀, ó ti fihàn fún àwọn ẹni mímọ́.

Kólósè 1

Kólósè 1:17-29