Kólósè 1:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó ti wà ṣáájú kí ohunkóhun tó wà, nínú rẹ̀ ni a sì so ohun gbogbo papọ̀ sọ̀kan.

Kólósè 1

Kólósè 1:13-20