Kólósè 1:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

pé kí a lè fi ipa gbogbo sọ yín di alágbára gẹ́gẹ́ bí agbára rẹ̀ àti ògo rẹ̀, kí ó lè ṣe é ṣe fún un yín láti máa tẹ̀ṣíwájú nínú sùúrù àti ìpamọ́ra pẹ̀lú ayọ̀.

Kólósè 1

Kólósè 1:1-14