Júdà 1:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bákan náà ni àwọn wọ̀nyí ń sọ ara wọn di èérí nínú àlá wọn, wọ́n ń gan ìjoye, wọn sì ń sọ̀rọ̀ búbúrú sí àwọn ọlọ́lá.

Júdà 1

Júdà 1:4-14