Júdà 1:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

tí Ọlọ́run ọlọ́gbọn níkan ṣoṣo, Olùgbàlà wa, ní ògo àti ọlá ńlá, ìjọba àti agbára, nísinsìn yìí àti títí láéláé! Àmín.

Júdà 1

Júdà 1:16-25