Júdà 1:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí wọn ti wí fún yín pé, “Nígbà ìkẹyìn àwọn ẹlẹ́gàn yóò wà, tí wọn yóò máa rìn gẹ́gẹ́ bí ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ àìwà-bí-Ọlọ́run ti ara wọn.”

Júdà 1

Júdà 1:11-21