Júdà 1:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n jẹ́ ìjì líle ti ń ru ní ojú omi òkun, ti ń hó ìfófó ìtìjú wọn jáde; alárìnkiri ìràwọ̀, àwọn tí a pa òkùnkùn biribiri mọ́ dè láéláé.

Júdà 1

Júdà 1:9-18