Jóṣúà 9:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ìránṣẹ́ rẹ ní àwa í ṣe.” Wọ́n sọ fún Jóṣúà.Ṣùgbọ́n Jóṣúà béèrè, “Ta ni yín àti pé níbo ni ẹ̀yín ti wá?”

Jóṣúà 9

Jóṣúà 9:1-14